Ti akosile ko ba si mi lona, ojo ketadinlogbon osu kesan-an odun 1954 ni won bi Bisoobu Oyedepo ni ilu Oshogbo oroki. Baba naa pinnu lati tele Jesu Oluwa Olugbala araye lojo kokandinlogun osu keji odun 1969. O da ijo Winners'Chapel sile lodun 1981eleyii ti owoja ijo naa ti na kari gbogbo aye.
Aimoye awon eniyan mimo ati olokiki ni won peju sibi ayeye ojo ibi ogota odun Bisoobu, lara won ni Dadi G.O ti ijo Irapada, Pasito E.A Adeboye ati awon eniyan kanrikanri lawujo.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment