Okan ninu awon olubori idije Big Brother Africa nigba kan ri, Karen Igbho wa ni Ilu Amerika bayii.
Akiyesi mi nipa foto omobirin naa to te mi lowo fihan wi pe o ti ru die ju ti tele lo. Ti e ba wo aya omo naa nigba to wa ni inu idije BBA, e o gba pelu mi wi pe lotito lo ti kere sii.
O si le je omo naa lo lo din eru aya re ku. Nitori o ti so ri wi pe oun ro omi die si eji-ogbe aya oun ni tori ko le ta jade daada.
Laipe yii naa ni omo naa ni arun jejere eleyii ti won ti se itoju re ni ilu London.
Apapo nnkan mejeeji le fa idi pataki ti omo naa fi ru.
#Gbeborun.com
0 comments:
Post a Comment