Edumare gba wa lowo eni ti n so wa ta o mo. Odaju laye, ika si ni eniyan. Edumare ma fi abo re to daju bo mi ati awon ololufe mi pata. A ko ni ko sowo ota ti n sebi ore.
Iku ojiji ko ni yale gbogbo wa. Edumare ko ni fi wa le ota lowo. Eni eleni ko ni gbase wa se. Ni agbara Olorun, gbogbo awa ti a ri ibere odun yii ni a ma ri opin re lase Edua oke.
E sora o! Ko seeyan mo. Ore ko si mo, abanirin loku. Eni ore da ko ma se binu, abinibi n da ni.
0 comments:
Post a Comment