Smiley face

Won Ti Pa Oga Oniroyin Ni Ilu Eko

Ogbeni Dimgba Igwe to je igbakeji alase ati olootu agba fun ile ise iwe iroyin SUN lagbo wi pe moto kan kalu laaro ana ladugbo Okota to wa ni ilu Eko nigba ti baba naa n sere idaraya nigba to n sare lo legbe titi. Moto naa gba a, o si salo.

Oga oniroyin pada ku leyin ti won gbe de ile iwosan.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment