Smiley face

Boko Haram Ti Gba Ilu Lowo Goodluck Jonathan

Awon omo Boko Haram ti bere si ni se akoso awon ilu marun-un ni apa ila-oorun Nigeria pelu aimoye emi ti won ti fi sofo danu.

Awon ilu ti awon Boko Haram n se akoso le lori ni Bara, Bank ati Gulak ti won wa n Ipinle Borno, ati Madagali ati Bama to wa ni Ipinle Adamawa.

Bakan naa la gbo wi pe aimoye awon eniyan ni won ti sa danu ni gbogbo agbegbe yii.

#Iroyin Ni Soki

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment