Orileede Congo ja irawo Super Eagles lana Satide (6-9-14) ninu okan lara ifesewonse taani yoo kopa ninu idije boolu ile adulawo ti yoo waye lodun 2015. Ayo meta si meji ni won gba (3-2).
Ninu oro akoni-moogba ti Super Eagles, Stephen Keshi, o ni bi e ni wi pe oun ti mo wi pe iya ni Nigeria maa je lowo Congo ni nitori awon omo Nigeria ko lati fi isan si ifesewonse naa.
"I'm very disappointed. It was not just the result but the way we played in the first half. I was like a soothsayer because I saw it coming and I talked to the boys that they had to be aggressive and
first to the ball.
"I've played against the Congolese team before and I know they play tip-tap football. We scored the first goal and that was it. It's a shame that we had opportunities, mostly in the second half, but
we could not score," oro enu Keshi.
Nibayii, ipo keta ni Nigeria wa lori ate nigba ti South Africa se ipo kinni ti Congo si wa ni ipo keji, Sudan ni won wa nisale patapata labala isori ilu mereerin.
#Koko Iroyin

0 comments:
Post a Comment