Omo Aare ile Nigeria nigba kan ri, Olusegun Obasanjo, Adeboye Obasanjo to je okan lara awon omo ologun to wa ni Ipinle Plateau ni ota ibon awon Boko Haram ti ba nibi itaporogan to waye.
Won ti gbe omokunrin naa lo si ile iwosan bayii.
E kunrere iroyin mbo laipe.
0 comments:
Post a Comment