Sii Olayemi Oniroyin,
Mo toro aforijin lowo yin nipa bi ago mi se ja lori ila. Ninu oro ta so ku lori phone. E so wi pe e fe mo ohun ti awon Omoge Onidodo n se gege bi ise.
Se e ri group awon Omoge Onidodo je group awon omoge ti won ni talent orisirisi. Awon kan maa n jo, awon kan maa n korin, awon kan de le se theater daada. A de tun maa n se modeling naa.
Idi pataki ti a fi ko ara wa jo ni lati le ran ara wa lowo. Ko de si iru obirin ti ko le darapo mo wa.
Orisirisi party ni won maa n pe wa si ti a maa fi ijoko ye won si. A maa n jo fun awon omo olorin naa ninu fidio orin won.
Ohun ti mo fe ki e se fun wa ni ipolowo oja. Mo de fe ki e maa se afihan awon foto wa lorisirisi.
A tun maa se alaye siwaju sii ninu awon leta wa lojo iwaju.
E je ki n mo ero yin nipa awon alaye ti mo se soke yii. Thank you.
T. Bebe ( Omoge Onidodo)
0 comments:
Post a Comment