Smiley face

Oloyun Bora Sile Nihoho Niwaju Gbogbo Aye

Loju awon eniyan dudu ile Afirika, won le ka si radarada bi obe oloka. Sugbon loju awon eebo alawo funfun oge to gbamuse lojo loju ti won. Sebi ohun to koju seni kan, eyin lo ko si elomii. Bayii la n se nile wa, eewo ibomii ni.

Awon ti won damo kii beere alaye. Sugbo fun awon ti ko moo dojudoju, Alicia Keys ni oruko re. Okan ninu awon irawo olorin ilu Amerika si ni.

Nje ki lo le fa to fi bo ara re sile nihoho toyun-toyun?

Awon kan gba wi pe o seese ki omobirin naa ya iru foto yii ni ona ati se igbelaruge fun orin re kan to sese gbe jade.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment