Ede ajoji ni Dorobucci to je akole orin kan to n migboro titi eleyii ti ile ise orin Mavin ju sigboro. Orisirisi aheso ni o si n lo nigboro nipa akole orin naa.
Awon kan so wi pe ko ma lo je Doro ti won fi n fami ninu konga ni won wi. Nigba ti awon kan si ni oseese ko je ede lati inu egbe okunkun eleyii ti itunmo re gidi ko han si eniboodi.
Sugbon Dr Sid fi DoroSuuru ba awon Oniroyin soro, ohun ti DoroLere wi ni yii:
"Dorobucci means a person or an individual that is awesome, amazing,
rich, swagged-out, sexy and buff.
Any word that qualifies greatness, that's Dorobucci.
'Bucci' means anything that is amazing, fun.
Doro makes Bucci a person, Doro personifies Bucci so you're Doro, and I'm Doro. This table is Doro, anything is Doro."
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment