Iroyin to jade lati odo awon omo ologun ni wi pe okunrin to ti n fi ara re han gege bi olori iko Boko Haram, Abubakar Shekau ni awon ti yanju re danu.
Gege bi atejade won, won ni ninu ija nla to waye laaarin awon omo ologun ati iko Boko Haran to waye lojo ketadinlogun osu kesan-an odun ni Konduga, nibi ti awon omo Boko ti n fowo lale gege alase agbegbe naa ni eyin okunrin naa ti bale.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment