Smiley face

Won Ti Sare Gbe Ibrahim Babangida Lo Si Osibitu Ni Ilu Jamani

Olori orileede Nigeria nigba kan ri, Ibrahim Babangida ni won ti da pada si ilu Jamani bayii latari opa eyin ti n yo baba naa lenu.

Opa eyin yii ni won ti ba a sise abe le lori tele lawon igba kan, sugbon o dabi wi pe nnkan ko tun fararo mo fun IBB pelu bi won se gbe digba-digba nigba ti n pariwo eyin didun ninu aafin re to wa ni Minna lo si Germany fun itoju.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment