Smiley face

Eye Abami To Deeyan Ti Pada Ku Ni Ilu Eko

Iroyin kayeefi to sele lenu ojo meta yii ni agbegbe Oshodi nibi ti eye abami kan ti ba le ina elentiriki, se e mo wi pe ina oo mo eni o dahun. Oju ese naa ni eye abami naa jabo to si yirapada di obirin. Iroyin ti kan wa bayii wi pe iya naa ti ku bayii. Ki Olorun te mama si afefe rere.lol

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment