A ti gbo iku Pa Joshua Taiwo Ayefele eni odun merindinlogorin (76) to je baba Yinka Ayefele. Ipoti Ekiti ni baba yii ku si ni ilu ile re. E teti leko fun akotun iroyin. Gbogbo wa la o gbeyin arugbo wa. Amin
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment