Smiley face

Omoge Onibadi Olokiki Ilu Amerika Tun Jade Lai Wo Komu

Eniyan taa ba lori igi ope, oro re ti kuro ni sara le tabi o le. Ohun to daju ni wi pe omobirin onibadi olokiki ilu Amerika, Kim Kardashian n gbadun igbeyawo re pelu agbaoje olorin agbaye, Kanye West. E o le biliifu wi pe ninu ode tuntun ti toka-taye yii ti jo jade, Kim aya Kanye ko wo beresia si isale aso re. Bee aso to wo fele bi eti eleyii to se afihan gbogbo eroja iyebiye to ko sabe aso. Ohun to je olubori ibe ni ori omu omobirin naa ti n mi jolojolo bi epon ago labe aso pelu bi oyan re se n fo soke-sodo ti gbogbo re si n mi logbologbo bi igba ti eniyan ro omi sinu polibaagi pelu bo se n yan lo loju titi pelu oko re. 

Nigba ti oko iyawo ko kompleeni, ko ye ki eniboodi gbemu. "Gbogbo boo ti n se ni mo gbadun re" Kanye West lo so bee.



Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment