Mo je enikan to maa n lo opolopo Data nigba to je wi pe ayelukara ni mo n lo lati gbe awon iroyin mi jade.
Sugbon lojo kan, mo pade Ogbeni HACKMED to se ileri lati ta ilopomeji MTN data bundle fun mi ni iye owo ti ile ise MTN n ta ida kan ti won.
Mo koko sebi 419 ni bobo na. Awon oniro si ti ba eniyan rere je. Sugbon gege bi oniroyin, mo se iwadii re daada.
Nigba to ya ni mo ba ra kaadi egberun kan(1000) ni mo fi ranse sii lati ori BBM mi pelu nomba ti mo fe ra data bondu si.
Ka to sejupe, omokunrin naa ti transifa Data bundle ilopomeji ti mo maa n ra lowo MTN ranse si mi pelu iye owo kan naa.
Mo koko sebi mo n lala ni. Omokunrin naa pada pemi lori foonu, a jo soro daada.
Mo beere bawo ni data tie se je ilopo meji. O so fun mi wi pe oun fi opolopo owo tabua ra data naa lodindi ni bi igba ti eniyan ra oja inu kontena lodindi.
Ti oun wa n tun ta leyoleyo. Ko si si oniye owo te e fe ra ti kii ta.
Eyin tiatia, mi o fe ki e maa nawo yin danu lori data ni mo fi ni ki n jayin si.
Otito ni o. E yin naa e danwo. Sebi Danwo lo bi iya Okere. Eniyan kii si gbe okeere mo didun osan. Sunmoni bayii laa mose eni. Ilopo meji data bondu lo n ta ni isiro owo ida kan soso ti ile ise MTN n ta.
Awon ona ti e fi le ba soro ni yii:
Call/Text 08167133533, Whatsapp: 08069698175, BB pin:26799941.
Olayemi Oniroyin ni oruko temi. Mo ti maa n tenu mo tipetipe wi pe, ise iroyin sise ko yato si ise awo. Babalawo to ba n paro, Ifa won ni i pon won laso. Oniroyin to ba n seke, iroyin won naa ni i so won doni yeye nigboro.
Mo ki yin ku odun ileya, opo re la o se. Amin!
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment