Gomina tuntun ni Ipinle Ekiti ti so fun awon oniroyin ni ilu Abuja wi pe awon eniyan oun se pataki ju lo. Ohun gbogbo ni oun si maa n se lati sun mo won ki oun le mo ohun ti won ba n fe. O ni eyi wa lara ohun to maa n gbe oun lo si ile oti ni gbogbo ojo Eti.
"I also go to beer parlour on Fridays
to stay with the common men there. Governance is not church; it is about diverse characters and you must relate with them as such."
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment