Leyin igba ti olori ile igbimo asoju-sofin Nigeria, Aminu Waziri Tambuwal ti kede fifi egbe PDP sile bo sinu egbe APC lojo isegun to koja yii eleyii to sokunfa bi ile ise olopa ile wa se ko awon osise alaabo re kuro leyin re.
Ohun ti a gbo bayii ni wi pe Aare Jonathan ti se ipade po pelu awon omo ile igbimo asoju-sofin kan ti ori won wa n be pelu awon oloye egbe PDP lori bawo ni won se fe yo Tambuwal danu kuro nile igbimo asoju sofin bi jiga.
Inu osu kejila ni ile fawo si lati pada joko tele sugbon pelu bi nnkan se n lo bayii, o seese ki ile joko lose to n bo.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment