Akoni-moogba egbe agba boolu Super Eagles, Stephen Keshi ni Aare Jonathan ti ni ki won lo pe pada wale lati maa ba ise re lo lakotun leyin ti won ti da duro lenu ise.
Ti e ko ba gbagbe, nnkan bi ose meji seyin ni ajo NFF san nigi lori wi pe ko maa lo si ile re ti won si fi Shaibu Amodu ropo re loju ese.
"This is not an FA decision; this was passed down directly to them from far above and the message was not passed through a third party in the
name of special adviser but a direct mouth to ear briefing." - asoju NFF
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment