Bi o tile je wi pe awon kan an pariwo wi pe awon ko setan lati dibo fun aare Goodluck Jonathan nigba keji. Bakan naa la tun ri awon kan ti won wi pe egbe alatako APC ko ni enikan gboogi to moyanlori to le gba ipo naa lowo Goodluck Jonathan oko Patience baba Elisabeti.
Nje lotito ni wi pe egbe APC ko ni oludije to giriki to le bori eto idibo aare ti n bo?
Ju gbogbo re lo, Ajagunfeyinti Muhammed Buhari si n lakaka lati je oludije labe egbe oselu APC.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment