Smiley face

Won Ti Da Stephen-Keshi Duro Lenu Ise

Ajo ere boolu Nigeria, NFF ti pada gba ise lowo akoni-moogba Stephen-Keshi ti won si ti fi ogbeni Amodu Shaibu ropo re ni kiakia.

Iroyin yii lo jade ninu atejade tuntun ti ajo NFF fi sita.

E tun bo foju sode fun akotun iroyin. E se pupo.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment