Balogun egbe agbaboolu ile South Africa, Senzo Meyiwa la gbo wi pe awon onise ibi kan ti lo figbon pa mo ile orebirin re to wa ni Johannesburg leyin igba to pari ifesewonse kan to waye.
Okunrin yii to tun mu goli fun egbe agbaboolu Orlando Pirates ni awon olopa ti jeri si iku to mulo sorun.
'We can confirm that Bucs (Pirates) keeper Senzo Meyiwa has been shot and sadly declared dead on arrival at hospital,' awon olopa.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment