Smiley face

Awon Adigunjale Ko Leta Si Awon Ara Eko

Awon eniyan ti won gbe ni Onimaba, to wa ni oju ona Ikotun ni Igando, Ipinle Eko ji laaro putuputu pelu opolopo leta nigbogbo ayika won eleyii ti won se akiyesi wi pe awon gbewiri lo ko leta naa ranse.

Leta naa ni yii:

"Be prepared, be prepared, be
prepared. Our dues must be paid this
festive season. Nobody can stop us as
we can strike at any time.

Only enough money can save your life. To be forewarned is to be fore-harmed. We have warned you in this area, and if you have ears, you ought to hear."

Nibayii, won ti n fi asiko yii ke si awon alase osise alaabo lati se iranlowo fun won ni agbegbe naa.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment