Awon omo ile igbimo asofin Ipinle Ekiti bi meje lati inu egbe oselu PDP lagbo wi pe won joko lonii lati yo olori ile igbimo asofin ipinle naa, Omowe Adewale Omirin ati igba keji re danu lonii bi igba eniyan n yo jiga danu lese.
Nibayii, won ti fi Dele Olugbemi ropo gege bi olori ile tuntun.
Home / Uncategories / Gobe Si N Tesiwaju Ni Ipinle Ekiti: Won Yo Olori Ile Igbimo Asofin Danu Bi Jiga
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment