Mo salaye fun yin laipe yii nipa Sheu Salam, ebun pataki ti Olorun Oba Allah fi jinki awon eniyan dudu ni ile Adulawo, erusin Olorun tooto ti n fi imo ati agbara adura ran iran omoniyan lowo lati bo kuro ninu isorokisoro ti n koju omo eda laye.
Mo ti kan si Sheu Salam, inu akanse adura nla ni won wa bayii. Iru akanse adua nla bee kii se gbogbo igba lo maa n waye. Awon akoko yii si je eyi to lagbara gidigidi ti Olorun oba Allah n gbo ohun ti Sheu ba beere pelu aanu.
"Ohunkohun ti Olorun ba fun eda laye, fun idi kan pataki ni. Pupo ninu agbara ti Olorun si fun eda laye lo je lati fi saanu awon eniyan. Ko si agbara kan nibi kan ayafi Olorun, Olorun nikan lo si ni agbara gbigba adua lowo." Sheu Salam
E gbiyanju kee pe Sheu Salam lori ago bayii lati bayin fi oro yin siwaju Olorun oba mimo, oba alagbara laye ati lorun.
07065865035, 08113280526.
Olorun oba yoo gba adura gbogbo wa o. Amin.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment