Awon eniyan ti bere si ni dibo danwo-kawo-bi-o-ti-ri lori ikanni Yoruba Dun to wa lori Facebook nipa wi pe se Aare Goodluck Jonatha yoo pada wole eleekeji gege bi Aare ile Naijeria a bi beeko. Titi di akoko yii, awon eniyan bi irinwo (400) ni won ti dasi apero naa, nibi ti awon eniyan bi oodunrun (300) ti koyin si oko Patience. eyin naa le ye awon esi ibo naa wo [NIBI]
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment