Iroyin tuntun lati Ipinle Ekiti tun ni bi Egbe Onigbale se duro lorun Ogbeni Ayodele Fayose, eni ti gbogbo ara ilu dibo yan sipo lati kede dukia re fun gbogbo aye gege bi Kayode Fayemi se se nigba isejoba re to koja.
Alaga egbe APC ti Ipinle Ekiti, Ogbeni Jide Awe ti buta soju bayii lori 'mata' naa:
"He who must come to equity must come with clean hands. The governor of a state must declare his assets.
In fact, it is a constitutional provision. He (Fayose) must declare his assets and let people know what he was, what he is and what he will be by the time he is leaving office." Jide Awe.
Oro yii ni awon omo egbe PDP naa ti fesi le loro. Won ni: "shio, ki lo n se awon people yii naa? Oro ko si lenu atoole yin rara. N80b te e ji ko ninu apo ijoba se e ti dapada ni?"
E je ka gbo alaye to ku lenu Idowu Faleye to je alaga egbe PDP Ipinle Ekiti:
"If Fayemi has declared his own assets, he should say so publicly.
All the money he received should
be accounted for.
He should also declare his assets after his tenure in office.
"The normal practice is that when a governor comes in and after his exit, he must be able to declare all his assets and give account of how much has been spent from the allocation." Alaga Egbe PDP, Ekiti.
Gege bi afikun Jide Awe to je alaga egbe APC ti Ipinle naa. O ni gbogbo aye ni won ti mo Ipinle Ekiti gege bi tifunloran. O ni o si daju wi pe oju awon ara ilu yoo ja pelu ijoba ti won fi owo ara won gbe wole.
Home / Uncategories / Laaarin Fayose Ati Fayemi, Surutu, Wahala, Ijangbon Si N Tesiwaju Bi Fiimu To Gun Gan-an
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment