Sebi dida loda lomo degbe, egbe kii se ile omo rara. Ipile ile ise orin Mo' Hit ni Dbanj ati Don Jazzy je. Sugbon nigba to ya, ina ko wo mo. Aguntan ko si ni ohun ko ba ewure sore, ewure lo yari to ni awon kii sokan soso. Eyi lo fa ti Mo' Hit fi wo bi odi Jericho. DBanj lo, Don Baba si da ile ise orin tie sile to pe ni Mavins.
Lori alaye wi pe se aye Dbanj, Kinihun funfun, Eja Nla si sile leyin to fi awon egbe re sile ni Dr Sid ti fesi le lori.
"We are not missing Dbanj, no, not at
all.
He is doing so well and he has gone on to drop a couple of hits and the same goes for Mavin;
we have dominated the last two years of Nigerian music no doubt so we are also doing so well,"
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment