Smiley face

Omoge Onitiata Ko Odindi Oyan Meji Sita Gbangba

Oserebirin onitiata, Rukky Sanda lo gbe tuntun yo nibi ode ariya ayeye ojo ibi ore re kan to waye ni ilu London pelu Oge ati Ebube.

Ohun to jo ni loju ju nipa oge Rukky ni bo se pate odindin oyan meji sita fun gbogbo aye. Nje a le pe eyi ni oge tuntun abi oge agbasodi?

Temi ni lati se afihan ohun ti n lo, ti yin ni lati dajo ohun ti e ba ri.

E ku ikale!
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment