Smiley face

Won Ja Ewe Oye Le Atiku Abubakar Lori Ni Ipinle Ekiti

Won ti fi Igbakeji Aare ile Nigeria nigba kan ri, Atiku Abubakar Je oye Aare ti Ire-Ekiti ni Ipinle Ekiti.

Orisiirisii awon eniyan pataki ni Ipinle Ekiti ati lati inu egbe APC lo wa nibi iwuye naa, lara won ni gomina Ipinle naa nigba kan ri, Kayode Fayemi.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment