Smiley face

Alukawani Eru Olorun Ni: Dukia Te e Seleri Fun Wa Nko?- Golden Eaglets

Awon omo egbe agbaboolu ile Nigeria ti ojo ori won ko ju metadinlogun lo, Golden Eaglets ti n bebe fun imuse ileri ti awon gomina kan se fun won nipa wi pe ti won ba gbe ifi eye agbaye 2013, awon yoo da won lola.

O ti pe odun kan bayii ti awon omo naa ti gbe ifi eye naa wale sibesibe awon gomina yii ko ti mu ileri won se.

Awon ileri yii ni akoni-moogba egbe agbaboolu naa, Manu Garba ti n ro won lati muse ki ijoba won to kogba wole.

Awon gomina meji ti won se ileri ti won ko ti muse ni Gomina Liyel Imoke ti Ipinle Cross River ati akegbe re lati Ipinle Niger, Babangida Aliyu.


"Once again, I want to thank Governors Imoke and Aliyu for their moral and financial support to us when we won the World Cup last year but I want to use this opportunity to remind them of the house gifts and landed properties to us,"

"Though we have had assurances, I just want to remind our amiable governors that we are still waiting for these gifts," oro Manu Garba.

Olorun nikan lo le se ileri feda ti ko ni ye. Ti Obama gan-an ba seleri feniyan ki eni bee ma lo 'Behappy' lapoju nitori wi pe eniyan ni.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment