Iroyin ti kan wa wi pe oniwaasu ati oludanileko agbaye, Myles Munroe ati iyawo re ti lo sun laya olugbala latari ijamba oko ofurufu kan to waye ni Bahamas eleyii ti toko-taya naa wa ninu re. Gbogbo awon eniyan bi mesan-an ti won wa ninu baalu jeeti naa ni won segbe.
Myles ko ni oun o je mo, iku lo yo owo re kuro ninu awo tanganran.
Ogbontarigi maa sun laya olugbala.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment