Ayajo ojo oni ninu itan eleyii to waye ni odun 1995: Aare ologun Sani Abacha pase ki won lo seku pa Ken Saro-Wiwa nipa sisoko mo ori igi titi emi yoo fi jade lara re. Ken Saro-Wiwa ati awon eniyan bi mejo mii ni won ran nise lo sorun lodun naa ni ilu Porta.
Ken Saro-Wiwa je ajafeto-omoniyan eleyii to tun je olori egbe Ogoni. Abacha ri okunrin yii gege bi egungun eja lorun isejoba re, o si gbero wi pe yiyanju won lo le da alaafia pada si ile Nigeria.
Sugbon gege bi oro awon Yoruba, won ni iku yoo pa eni a n pe, iku yoo pada pa eni ti n pe ni. Ologbon aye, mo sebi e n kiye soro mi?
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment