Smiley face

Won Ti Se Nuhu Ribadu Leegun Eyin

Sani Ribadu to je aburo si olori ajo EFCC nigba kan ri, Mallam Nuhu Ribadu ni awon kan ti jigbe salo bayii ni ilu Yola.

Gege bi ohun ti a gbo, oseese ki isele yii waye lati se egun eyin Nuhu Ribadu nipa igbiyanju re lati di gomina Ipinle Adamawa eleyii ti okiki re ti kun igboro.

Aburo re ti won jigbe yii, Sani Ribadu naa ti fi igba kan je alaga ijoba ibile, bakan naa lo ti joko nile igbimo asofin ipinle naa tele ri. Okunrin yii kan naa si wa lara awon alamojuto igbimo e-dibo-fun-Nuhu-Ribadu ki won to jigbe nigba to se abewo sinu oko re nala ojo Kesan-an osu kokanla odun 2014.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment