Smiley face

P-square Pada Di Omo Orukan Leyin Iku Baba Won

Baba to bi awon omo ibeji olorin olokiki, Peteru ati Poolu omo Okoye lagbo wi pe o ti rebi agba n re lana ojo Monde (24-11-14). Isele yii lo waye leyin odun keji ti awon omo meji yii padanu iya won to wa won wa sile aye.

Ki Oluwa ba wa te Baba si afefe rere!
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment