Smiley face

Apapo Gbese Nigeria Ti Wo Tirinionu Mewaa Ati Binionu Mejo Owo Naira Ile Wa (N10.8tn)

Emi to je gbese naa ni o san. Ko si giri!

Apapo gbese owo ti Nigeria je, pelu awon ipinle merindinlogoji to fi mo olu ilu Abuja lo ti to nnkan bi N10.8tn. Awon owo yii ni awon owo ti won ya lowo awon banki okeere ati awon owo ti ijoba ya lowo awon ilu nlanla lagbaye.

Pupo ninu awon owo yii ni won na lori ina monamona, eto ilera, awon opopona wa gbogbo, ati eto eko, eto abo ati bee bee lo.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment