Smiley face

Won Ti N Soro Ile Fun Baba Kabiru Ni Ilu Oshogbo

Won ti bere ayeye iyansipo eleekeji Ogbeni Rauf Aregbesola Baba Kabiru gege bi gomina Ipinle osun (State of Osun) fun igba keji bayii ni papa isere Osogbo City Stadium.

Ti e ko ba gbagbe, ojo kesan-an osu kejo odun ni gbogbo Ipinle Osun pinnu lati fi igbale gba omi danu segbe kan ki won le raye dibo fun Aregbe.

Baba Kabiru lo lonii ni ilu Oshogbo, dem say dem say ko komfaamu gidi ni. Edua loni ojo gbogbo laye.

Kongiratulasan! 

Awon afikun foto si n bo lona...
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment