Ni Aaro oni Ojobo [ 27-11-14] awon ebi olokada yari siwaju ago awon olopa to wa ni Gbagi Tuntun ni ojo ona Ife atijo.
Iroyin
ti a gbo ni wi pe owo te awon olosa kan ti won maa n ja okada Bajad gba
lowo awon olokada ni agbegbe naa. Isele aaro yii gbinaya latari isele
to sele nijeta nigba ti awon ole kan pa olokada ki won to gbe okada re
tuntun salo.
Ohun ti awon olokada fe bayii ni wi pe ki
awon olopa fa ole ti won mu laaro yii le won lowo ki awon se idajo owo
awon fun won. Awon olopa ni ko joo, ni oro ba di gobe.
0 comments:
Post a Comment