Iroyin ti kan wa wi pe awon omo aye kan ti yalu egbe APC nibi won ti n mura ati bere ipolongo ita gbangba. Awon agba egbe APC ni Ipinle naa ti di ebi isele naa ru egbe PDP. Won ti le oro naa mole ni, won Goodluck lo ran awon omo aye naa lati wa da agbegbe naa ru. Aimoye dukia lo sofo lonii.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment