Ariwo so ni Ipinle Ekiti lonii nigba ti Buhari wole pelu awon agbaagbe egbe APC. Ariwo ti Fayose ti n pa saaju onii ni wi pe ko si enikan ti yoo tele Buhari ni Ipinle Ekiti. Sugbon oro yipada nigba ti GMB wole pelu igbakeji re. Oba orin wa lara awon olorin ti won pitu nibe, Akorede Saheed si n kede fun gbogbo Ado wi pe egbe onigbale lo le yanju isoro Nigeria.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)

























0 comments:
Post a Comment