Awon Yoruba ni bi eniyan ba bu
oba leyin, to si de iwaju oba to ni oun ko wi bee mo. A je wi pe ka gba wi pe
ko wi bee naa nu-un. Leyin igba ti Sammie Okposo, okan lara awon olorin emi to
tun un se atileyin fun Aare Goodluck Jonathan ti so ninu atejade re kan wi pe o
ye ki won ko egba fun Buhari pelu bo se n paro nipa ayederu sabuke ti n gbe
kiri ni.
Ana ni Sammie Okposo soro yii lori ero twitter re. Sugbon nigba ti ile
o fi mo lonii, omokunrin naa tun yii oro pada. Oni infomasan ti oun gbo lo si
oun lokan, ati wi pe ko si aridaju wi pe ayederu ni sabuke Buhari. O ni ki Buhari maa binu nipa oro abuku ti oun
so sii gege bi agbalagba to le bi oun lomo.
Ki lo le mu maanu yii tuuba? Se kii
se wi pe eru n ba nitori wi pe ko si eda to mola. To ba lero wi pe Goodluck ni
o wole sugbon to ba pada je Buhari nko? Ohun ti o teyin re jade ko ye
enikan. O le je ohun ti n baa leru
nu-un. Sugbon awon Yoruba ni eniyan kii dehin ka ko tun ma fi owo boo. A se Bobo
Sammie Okposo yio le rara. Sio!
E yin temi, e maa gbegbe lati
tele mi lori ero twitter nibi mo ti n pidan oju ese. Oju opo mi ni @OlayemiOniroyin



0 comments:
Post a Comment