Smiley face

Awon Ọmọde N Sa swiiti Ati Singọọmu Ninu Gọta: PDP Dabira Ni Ilu Eko

Ẹgbẹ oselu PDP se ipolongo lonii ni agbegbe Ojodu to wa ni ilu Eko, opolopo swiiti ati singọọmu ni won fon si gbogbo awon eniyan ti mbẹ loju popo. Die ninu awon swiiti ati singọọmu naa ko sinu gọta, sibesibe awon omode si n sawon.

Iya n je opolopo awon eniyan, Olorun oba nikan lo le mu iponju kuro ni ile wa. Adura mi ni wi pe ki Olorun fun wa ni olori rere ti yoo yi igba pada fun wa ni iluNigeria.




Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment