Amber Rose, gbajugbaja onkorin takasufe ilu Amerika
si wa leti odo ni ilu Miami nibi to ti n jaye alatika. Ibe naa ni Omobirin yii
ti juko oro si awon eniyan ti won soro alufansa sii nipa awon aworan aramonda
re ti n fon sori ayelujara lenu ojo meta yii. Oro ti beebi naa so ni yii:
"Omg ur a Mother put some clothes on'.Kiss my MILFY ass!"
0 comments:
Post a Comment