Smiley face

"Ko Tii Wu Mi Lati Ni Iyawo Nile" -Pasuma

Oga Nla ti pada so fun awon oniroyin wi pe igbe aye oun dun, bi o tile je wi pe oun ko ti laya nile, ati wi pe enikeni ko le mu oun se oun ti ko ti okan oun wa. Osere onifuji to ti to eni odun mejidinlaadota (48) se alaye wi pe aya wu oun naa sugbon ko ti to asiko. Pasuma ti o ti bi omo bi mefa sita lagbo wi pe o un kolabo pelu Ayo Adesanya ni awon igba kan, sugbon ajosepo won ko gun rege mo nikete ti awon eniyan fura si won.

Igba wo wa ni Paso 1 fe se igbeyawo ti yoo kuro ni baba n dagbe?

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment