Oko Ajagbe kan ni o ti sare wo ofiisi awon osise asobode ile Nigeria to wa ni Mile 2 ni ilu Eko. Ohun ti a gbo ni wi pe awon osise LASTMA kan ni won n lo siarin mo awako naa lowo nigba ti won gbiyanju lati da duro eleyii to pada yori si ijamba oko. Awon dukia lasan lo so ninu ijamba naa, emi kankan ko ba isele naa rin.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment