Smiley face

Awon Omo Ologun Nigeria Fi Emi Awon Boko Haram Sofo Laaro Oni Ni Ipinle Borno

Ojo gbogbo ni tole, ojo kan pere ni tolohun. Owo palanba awon omo Boko Haram segi laaro oni nigba ti won kolu agbegbe Biu to wa ni Ipinle Borno. Nibi won ti fe bere ise ibi owo won ni awon omo ogun Nigeria ti ya de ti won si sina ibon bo won bi agbara ojo.



Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment