Smiley face

Gobe Ti Sele Ni Ilu Abuja: Won Ni Aare Jonathan N Gbiyanju Lati Sun Eto Idibo Siwaju

Awon eniyan ti tu jade ni ilu Abuja lati fi ehonu han pelu awuyewuye kan nipa wi pe Aare Goodluck Jonathan n gbiyanju lati sun eto idibo siwaju yato si ojo kerinla osu keji odun ti gbogbo awon omo Naijeria n reti.

Oro naa ti da gobe sile ni ilu Abuja bayii pelu bi awon kan se n fara ki wi pe ko gbodo je bee.

Kini ero ti yin?
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment