Smiley face

Asiri Iyawo Ile To Yanle Ti Tu Sowo Oko: Ohun Ti Oko Re Se Fun Ni Yii

Fidio awon aworan yii lo ti di gbajugbaja lori ikanni Youtube nibi ti okunrun kan ti n koya fun obirin kan. A ko le so pato ohun to sele gan-an ni gidi. Sugbon gege bi alaye eni to gbe fidio naa sori Youtube se so, O ni oko obirin naa ka iyawo re papo mo ale. A ko le so ibi ti isele naa ti sele. Sugbon ko daju wi pe naija ti wa yii ni. O seese ko je okan lara awon ilu to wa ni ile adulawo ni sa. Ko si ohun ti maanu na ko fi na iyawo re, bo se n ko igi boo lori bee ni i ta ni ipa nikun. To ba tun ya, a tun la ori omobirin naa mole bi eni wi pe o fe seku pa patapata.

Sugbon ibeere mi ni wi pe, nje oda okunrin naa loju wi pe omobirin naa n yale ni tooto abi o kan fura si lasan ni?

Ibeere keji: Se omokunrin yii le bura wi pe oun naa ko yan ale ri?










Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment