Awon Yoruba ni airin jinna lairi abuke okere, ti eniyan ba rin titi yo ri ibi won ti n fi odo ibile jeun. Ni abule kan to wa ni ilu China ni iroyin ti kan wa wi pe won so omodekunrin kan sinu omi leyin ti won ti mole fun ojo kan latari wi pe omode naa jale. Jin Hung, omo odun mesan-an ni iwadii fi ye wa wi pe o ti n jale tipe ko to di wi pe owo palanba re segi eleyii ti awon eniyan abule naa si ko lati darijin; ti won si pinnu wi pe dandan ni ki awon fi jofin. Die loku ki won gba emi omode yii, opelope awon olopa ti won wa gba omo naa sile leyin ti awon obi re ke gbajari.
E ja Ka gbo die lara ohun ti Yuan, okan lara awon ara abule naa so:
"We all knew in the village that there was somebody stealing, if it wasn't eggs from our henhouse or vegetables, it was cash from inside empty properties.
"When he was caught red-handed we went round to his house and demanded to see inside his room, where we found a jar filled with money hidden under his bed," Yuan salaye.
"This was obviously his ill gotten gains, and he needed to be taught a lesson that stealing is wrong."
0 comments:
Post a Comment