Oba Lamidi ni Alaafin asiko yii. Bi won ba n pe oba l'Alase-Ekeji Orisa bi ti Lamidi ko. Oosa gan-angan ni Lamidi. Aye ye Lamidi Olayiwola Adeyemi III ni Ilu London, eni ti a bi ni ojo keedogun osu kewaa odun 1938 (15 October 1938).
Ni Ifafiti ti Ilu London ni won ti fiwe pe omo Adeniran gege bi alejo pataki nibi ti awon oyinbo ti n fi oye Dokita da Aare Afe Babalola lola. Baba ni kan ko lo lo, awon olori bi meji naa tele baba ki ode le dun daada.Itan so fun wa wi pe Alaafin Gbadegesin Ladigbolu II lo ti n je ki Lamidi Adeyemi to bo si ipo baba re ni odun 1970.
0 comments:
Post a Comment